Apeere gbolohun ase lesson note Femi pari idanwo. Won wo aso, won si wo bata. Editable and printable format. Oro – oruko pelu eyan. Litireso –Atunyewo orisii eya litireso,ohun ti litireso je Awon eya litireso. O. Ipo Abo :- Eyi ni olu faragba nnkan ti SS 2 THIRD TERM YORUBA LESSON NOTES. Oro aponle ni a n lo lati yan tabi se afikun itumo fun oro ise tabi apola-ise ninu gbolohun. Owe ni awon oro ti itumo won jinle ninu asa. GBOLOHUN ALAKANPO( Compound sentence)Gbolohun alakanpo ni inu gbolohun ti a ti maa n lo oro asopo kan [] OSE KEJIAROKO ALALAYE AKOONU: Aroko Alalaye Ilapa eroAroko alalaye ni a fi n se ekunrere alaye lori ori-oro kan ti eni ti o ba ka aroko bee kofi ni ni isoro lati mo ohun ti alaye wa da le lori. Apola Oruko le je: Oro Oruko eyo kan ni ipo oluwa tabi ni ipo abo. Ami ohun lori awon faweeli ati oro onisilebu kan. Ibudo Itan. Apeere ; Sola lo si iwo. Ti a ba fe ko aroko bayi, a This lesson note covers the following topics for JSS2 First Term Yoruba: Sise atunyewo fonoloji ede Yoruba; Atunyewo awon asa ninu ise olodun kin-in-ni. Oruko omo ni Click to read:Akole Ise:- Ede:- Awon isori gbolohun Yoruba gege bi ise won. Fun mi ni omi mu; Jowo maa bu mi mo; Bami toju re daa daa; Gbolohun Ayi sodi:Gbolohun yii maa n fihan pe isele kan ko waye. EDE – Awe gbolohun ede Yoruba: Oriki ati alaye kikun lori awe gbolohun; Orisi awe gbolohun; Olori Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Eyi ni gbolohun ti a fi oro asopo kanpo mora won. Iwe mewaa ni mo ka. Gbolohun Ase: Eyi maa n waye nipo Pelu apeere mete mete, salaye ise oro oruko meta ninu gbolohun. com online secondary school 3 SS3 First term. Síńtáàsì ni èka kan nínú gírámà èdè tí ó níí sè pèlú bi a se ń so òrò pò tí ó fi ń di gbólóhùn àti bí a se ń fún gbólóhùn yìi ní ìtumò. OSE KIN-IN-NI AKOLE ISE-ATUNYEWO ISE SAA KIN-IN-NI OSE KEJI Apeere Ori oro Aroso Asotan 1. LITIRESO: KIKA IWE EWI TI IJOBA YAN. Fún àpeere, eni tí ó bá gbó èdè Yorùbá dáradára yóò mò pé (1a) ni ó tònà pe (1b) kò tònà, (1) (a) Mo lo sí oko This lesson note covers the following topics for SS1 First, Second and Third Term Yoruba: FIRST TERM. ORISIIRISII GBOLOHUN OLOPO ORO-ISEGbolohun olopo oro-ise OSE KARUN-UNAWE GBOLOHUN EDE YORUBA. - ise ti oro oruko n se ninu gbolohun. Gbolohun onibo ni eyi ti a fi gbolohun kan ha ihun omiiran. Oro Oruko tabi ‘ase jere ni temi’ je apeere gbolohun (a) ayisodi (b) oniroy ni (d) ijehen; Mastering Spreadsheet Features: From Rows to Charts Computer Studies JSS 3 First Term Lesson Notes Week 10; Digital Literacy in Action: Transforming Education, Employment, Alaye lori itumo oro ati gbolohun onipoona; ASA – Eewo ni ile Yoruba: Kini eewo/orisi eewo; Orisirisi eewo ati itumo okankan won; Ki ni o maa n sele ti eniyan ba deja eewo ati atunbo tan re; LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan . EDE: Aroko Onisorogbesi - D. Dọ́kítà kọ́ oògùn àti abẹ́rẹ́ fún un. Itunmo re ni beeko. apeere ‘Bolu je akara. Salaye ipa/isemeta ti awon egbe Ogboni n ko ni ilu. - lilo oro oruko ninu gbolohun. Bi apeere: gbolohun abode. Orisii eya gbolohun meji ni o wa. Okiki(2012) ASA:- Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan Read More » Ede:- Akaye oloro geere ISE-:EDE YORUBA CLASS: S. Awon Yoruba tile gba pe won maa n na oja ale. What you'll learn. Asa: Oge sise ni ile Yoruba. JSS 3 FIRST TERM LESSON NOTE YORUBA – EduDelightTutors JSS 3 FIRST TERM LESSON NOTE YORUBA. 2,Kin ni oge sise? b. ETO ISE FUN SAA KEJI. Awon eya naa ni: (i) gbolohun ni ilana ihun ati (ii) gbolohun ni ilana ise tabi ise ti o n je. 1. Ohun ti a mo si awe gbolohun ni tire je apa kan odidi gbolohun. Skip to content. WAEC/NECO. Ohun kan naa ni opomulero to n toka isele inu gbolohun. To download First Term JSS1 Yoruba Lesson Note, scroll up and click on the “order Gbolohun Ase: Eyi ni gbolohun ti a fi n pase fun eni ti a n ba soro. Gbolohun: Alábọ́dé Alakanpo Oníb “Olu ti mu igi naa wa” je apeere gbolohun (A) ibeere (B) alaye (C) ase (D) atokun ‘Yara pada” je gbolohun (A) ibeere (B) alaye (C) ase (D) SECOND TERM LESSON NOTE PLAN SCHEME OF WORK FOR NURSERY, KG, PRIMARY AND SECONDARY SCHOOLS; All Subjects Primary 3 Second Term Lesson Notes; Learn online with very engaging video lessons, ebooks and audio lessons Our Library . OSE KERINISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISEKo si bi eniyan se le wa ti ko ni se amulo gbohun bi ti wule ki o ri, eeyan gbodo se amulo gbolohun ayafi ti eniyan ba je odi loku. Omo naa kigbe bi eni ti agbon ta (b) Awe gbolohun afarahe asaponle alasiko eyi maa n toka asiko ti nnkan sele ninu gbolohun tabi igba. Apeere: 1. READ ALSO. Akoko ni leta gbefe (informal letter) nigba ti ekeji je leta aigbefe (formal letter). Primary Video Lessons Primary Audios Akekoo yoo le so ise ti oro oruko ati arọ́pò oruko n se ninu gbolohun. FIRST TERM E-NOTE SUBJECT: YORUBA CLASS: SS1 Ilana ise fun saa kinni Ose kinni-Ede Atunyewo awon eya ifo -Eyi ti a le fojuri ati eyi ti a o le fojuri -Afipe asunsi ati akanmole Asa- Owe lorisiirisii-owe imoran ,ibawi abbi. Mo pe won. OWE. Atoka/wuren gbolohun onibo ni: ti, ki,iba,ni,pe,nigba,bi. O sanra ona ko gba je apeere Gbolohun alakanpo oloro-ise (a) Apaaro (b) onilodisi (d) alaijowa APA KEJI. Won asi maa yipada si eniyan nigba ti o ba wu won. Our Library . Gbolohun ase ni a gi npase fun eniyan bi apeere:JOKO ,DIDE. Gbolohun: Oro-oruko ti a Onkowe Yoruba ti ko bam o nipa awon orisa ile Yoruba ko le ko iwe to ye kooro ninu asa. Koko Ise: Ise oro Ise ninu gbolohun Oro Ise ni emi gbolohun. Awon oro asopo ti a le fi so gbolohun eleyo oro-ise meji po ni wonyi, Ayafi, sugbon, oun, ati, anbosi, amo, nitori, pelu, tabi, koda, boya, yala abbl. Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le: OSE KESAN-ANEYA AWE GBOLOHUN Gege bi a so saaju pe awe gbolohun pin si meji: olori awe gbolohun ati awe gbolohun afahe. Apeere;Yetunde sun fonfonEpo wa ni Sapele. Ipo Oluwa :- Eyi ni oro oruko ti o jeyo ni ibere gbolohun tabi ti o je oluse isele inu gbolohun. Ise oro-aponle ni lati se afikun itumo fun apola-ise ninu gbolohun lati mu ki itumo re yeni yekeyeke si bi apeere: Tun n rin werewere lo si ile. apeere; Wa, jokoo, dide, jade. EDE: Aayan Ogbufo wuuru titumo eyo oro gbolohun ede geesi si ede Yoruba. Apeere: Ile wo. ASA – Eto ogunjije. Ero ati itumo gbolohun maa n kun Fun apeere OSE KEJIAROKO LETA AIGBEFELeta kiko je ona kan pataki ti a n lo lati ranse si ara eni. Apeere: ade pa eku. Isori oro +ninu gbolohun; Isinku nile Yoruba. rånti åwon eko ateyinwa ii. Apeere oro ise ni: lo, sun, sare, jeun, se, wa, ri, han, ropo, duro, jokoo, rerin-in, dide, korin, sunkun, wo, pade, ro, ka, pade, to, to abbl lesson, and a personalized learning dashboard that empower learners to study at their own pace OSE KEWAAORI-ORO-;ISORI ORO-ORUKOAKOONU- oriki- orisiirisii oro oruko. Apeere iwe to samulo awon orisa ni Oba Koso ti Duro Ladipo ko Koko Ise: Ise oro Ise ninu gbolohun. Apeere Kola ya iwe. Kin ni gbolohun olopo oro-ise? b. Ori odo silebu ni a maa n fi ami ohun siKan-an-n-pa ni odo silebu je ninu ihun . Apeere aroko alarinyanjiyan. Asa: Oge sise ni ile Yoruba . OSE KESAN-ANEYA AWE GBOLOHUN Gege bi a se so saaju pe awe gbolohun pin si meji: olori awe gbolohun ati awe gbolohun afarahe. Olu n ‘ro’ amala ni ori ina. O si maa ni oro asopo ninu pelu. Orisi awe gbolohun meji Pataki ni a le fa yo ninu ihun gbolohun . Litireso: Orin ibile to je mo asa igbeyawo, pipa ogo obinrin. Sise asunki odidi gbolohun di oro-oruko. fun apeere. 00. Apeere:Mo jeun mo si yo. Apeere: ojo ro ni ana. Baba ko yo. i. lesson, and a personalized learning dashboard that empower learners to study at their own pace in and outside of the classroom. Bi apeere: Ile re tobi, iyara re kere = ile re tobi sugbon iyara re kere. Apeere: jokoo si ibe yen, pa enu re de. AKOONU: -Gbolohun oniponna-; ni gbolohun ti o ni ju itumo kan lo. Bi apeere: i. Gbolohun Alakanpo: Gbolohun alakanpo ni gbolohun ti a ti fi oro-asopo so awon gbolohun miiran po di eyo kan. Apeere: Emi ni won n ba wi. Asa : Asa iranra-eni lowo. EDE – Itesiwaju eko lori oro ise; Alaye lori orisii ati ilo re ninu gbolohun. eyi le jeyo ni aarin tabi ipari gbolohun. Ose keji-Iro-ede Yoruba Ohun - OSE KERIINIPAROJE ATI ISUNKIAKOONUIparoje: Ni fifo awon iro tabi siso awon iro nu nigba ti a ba n yara soro. Gbolohun Alakanpo. Awe gbolohun pin si orisii meji. Mo sun . OSE KEFAORI ORO-SILEBU NINU EDE YORUBA -ORIKI -IHUN -BATANI -ODO ATI APALA SILEBU AKOONU Odo silebu;ni apa to gbe se pataki julo ninu ihun silebu kookan. Jide gun igi giga fiofio. ASA: Eto ogun jije I: oriki, iyato laarin ogun baba ati ogun iya, ona ti a n gba pin ogun, awon ti o ni eto si ogun pinpin Gbolohun ni Ilana Ise /ise ti o n je: apeere gbolohun alalaye, ase, ibeere, kani, ayisodi, View More. Orisirisi bii iku se n pani apeere, aisan, ijamba lorisirisi, afomowofe ati bee bee lo Awe gbolohun afarehen. ASA: Awon asa to suyo lati inu orin etiyeri ati dadakuada. Physical and Health Education Lesson Note JSS1 Second Term. Iyan naa kan . LIT: Itupale lori iwe Litireso ti Ajo WAEC/NECO yan fun S. Gbolohun alakanpo Gbolohun ase Gbolohun ibeere. Ti a ba n yara soro, a maa n pa awon iro kan je, awon iro ti a maa n paje ni: Iro konsonanti. Kin ni egbe awo? b. Fun apeere. 5 ÈDÈ: Onka Yoruba lati ookan de aadota [1-50]. Asa : Isinku nile Yoruba. Litireso Apileko. Tel:+23412952086; OSE KERINAKORI ORO: - EYA GBOLOHUN EDE YORUBA AKOONU: -- Gbolohun eleyo oro ise - Gbolohun olopo oro ise - Gbolohun alakanpo - Gbolohun ase - Gbolohun ibeere Gbolohun ni ipede ti o kun. LITIRESO – Awon eka ede OSE KERINEYA AWE GBOLOHUN AFARAHEAKOONU:- Awe gbolohunafarahe Olori Awe GbolohunORISII AWE GBOLOHUN AFARAHEOrisii awe gbolohun afarahe meta ni o wa ninu ede Yoruba, awon meteeta ni: -(a) Awe Gbolohun Afarahe Asodoruko: eyi maa n sise oro oruko ninu gbolohun. Bi apeere: Request for Lesson notes/plan, Scheme of Work, Examination Questions, School Resources for Nursery, Primary and Secondary School by Clicking or Taping any of the contact below our WhatsApp Line Gbolohun alakanpo :- Gbolohun yii ni a maa n fi oro asopo so awon gbolohun miran po di eyo gbolohun kan. apeereO lo [ eyo ni o ]Won wa [ opo ni won] oro SS 2 FIRST TERM LESSON NOTE YORUBA – EduDelightTutors. AKOONUAwe gbolohun je ipede to ni oluwa ati ohun ti oluwa se (oro-ise). Fun apeere. Apeere:- Ife ra fila. Here you can learn Yoruba language for Senior Secondary School online free of charge at no cost. Olùwa: • Igi wo • Mo lo si oja Abo fun oro ise: • Olu ko iwe • Baba na an Abo fun oro atokun: Isori oro +ninu gbolohun – EduDelightTutors. Bi apeere:-Dupe ‘pon’ omi. Iyawo kan ni o ye okunrin. ORO – APONLE: Awon oro ti o maa n pon oro – ise le ninu gbolohun ni a pen i oro aponle. Daruko orisii ona ti a n gba soge ni aye atijo. Eko lori igbadun ti o wa ninu litireso alohun. Atunyewo awon ewi alohun yoruba. I / we = 2 Ba / ta = 2 Ihun silebu:- Ona meta Pataki ni ihun silebu pin si awon naa ni:- Ihun faweli kansoso Ihun to je OSE KESA-ANEDEAPOLA APONLEOro aponle ni awon oro tabi akojopo oro to n sise aponle fun oro ise. Apeere:Femi waSola sun. Ayipada to ti de ba Asa isinku abinibi tabi atohunrinwa LITIRESO – Agbeyewo iwe ti Ajo WAEC/NECO yan. LITIRESO – Itupale asayn iwe lati ajo WAEC/NECO yan: 3 OSE KEFAORO AROPO AFARAJORUKOOriki Abuda oro aropo afarajoruko Irisi oro aropo afarajoruko. ASA – Atunyewo asa iran a enilowo, owe, aaro, obese, esuse, ajo. Awe gbolohun pin si ona meji. Ayeye ere onilejile ti o koja ni ile-iwe mi 3. ASA ISOMOLORUKO. Ki ni gbolohun (sentence)? Gbolohun ni ipede ti o kun, ti o ni itumo, ti o si ni ise ti o n je. Tisa na omo naa. Atunyewo awon eya ara ifo; Atunyewo Eko ile- asa ikini . Fun apeere: 3, Opopona Akanlo ede ni awon oro ti Our mission is to provide a world‑class education for anyone, anywhere. Apola-ise le je: Oro-Ise Alaigbabo. Sade 'ra' bata. Itesiwaju lori eko nipa iro ede; Ise abinibi. Eda Itan. Asa Awon akanlo ede Yoruba Lit Kika iwe adugbo,opopona, ipinle. Gbolohun-; ni ipede ti o kun to si ni ise ti on je. Bola jeun ni ori tabili Sade ra aso ti ko ni iho lara Click to read:Akole Ise:- Ede:- Awon isori gbolohun Ede Yoruba Gege bi Ihun - Discover insightful and engaging content on StopLearn Explore a wide range of topics including . AKOLE ISE Itan Isedale Yoruba. Apola oro oruko ni eyo oro oruko kan tabi meji tabi ju Third Term SS2 Mathematics Lesson Note ₦ 500. GBOLOHUN ONIBO. Oro eda inu itan iwe re je oro tabi iwin. ORUKO ENIYAN : -Oro oruko le je oruko eniyan,eyi ni oruko ti o n toka si ohun ti o je SS2 Online Class & Lesson notes; Sise asunki odidi gbolohun di oro-oruko. Gbolohun onibo ni gbolohun ti a fi ihun gbolohun miran bo laarin ,ki ole ni itunmo , kikun bi apeere:ILE TOBI —–ILE TI MOKO TOBI. Iwo ati Kayode niyoo soju wa. Apeere oro aponle ni daradara, kiakia, foo. Eda itan, ibudo itan. Gbolohun Ase: Gbolohun ase ni gbolohun ti a fi pase fun eni ti a n ba soro. Gbolohun Ase: a maa n fi ase. anfaani gbigbo oro ati riri aworan awon eniyan inu re wo je iranlowo ti ko ni afirwe ninu gbigbe ede ati asa Yoruba laruge. apeere. Apeere ; Dide duro; E dake jeje; Gbolohun Ebe :- A n lo gbolohun ebe lati fi bebe fun ohun kan. 2 ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KETA Ose: EDE: Aroko ti o je mo isipaya. 1. Fun OSE KERINISORI GBOLOHUN OLOPO ORO-ISEAKOONUGbolohun Olopo Oro- ise ni gbolohun ti o maa n ni ju oro-ise kan lo, o le je meji meta tabi ju bee lo. Sugbon ninu gbolohun olopo oro ise tabi gbolohun alakanpo ni a ti maa n ri awe OSE KKARUN-UN. apeere Gbolohun Oro-oruko ti a seda Oluwa to sin A kuru yejo Oluwatosin Onkowe Yoruba ti ko bam o nipa awon orisa ile Yoruba ko le ko iwe to ye kooro ninu asa. Wayio, Oro ise ni oro ti o n fi isele inu gbolohun han TABI ki a so wi pe oro ise ni opomulero gbolohun. ni a n lo lati fi kan gbolohun meji po. Ona kaan naa niyi ti a fi gbe ero eni si ori eto, ti Second Term SS2 Yoruba lesson note is ready for download. Bi apeere: Gbolohun Ase :- Eyi ni gbolohun ti a fi n pase fun eni ti a n ba soro. Pelu apeere meji meji, kini gbolohun; Ase ii. 2. Subject Scheme & Timeline: HIHUN ORIISIRISSI AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN ; Learn online with very engaging video lessons, ebooks and audio lessons. Adewoyin S. Subject Scheme & Timeline: ONKA YORUBA (301- 500) AROSO ALAPEJUWE ; AROKO ALAPEJUWE . Igi osan naa ga fiofio. Apeere: Bola mu oti yo. Bi apeere: Bisi sun; Dayo gun igi; iii. YORUBA LANGUAGE – JSS ONE. Ni opo igba a maa n ba won ni iwaju oro ise ninu gbolohun ni. Stay informed, entertained, and inspired with our carefully crafted articles, guides, and resources. i 211-217 IGBELEWON. Gbolohun ni Ilana Ihun ni: gbolohun eleyo oro ise (abode), olopo oro ise (onibo) ati alakanpo. Asa ati ohun-elo isomoloruko. Gbolohun Ase: Eyi ni gbolohun ti a fi n pase fun eni ti a n ba soro. Gbolohun ni a fi maa n se agbekale ero okan wa kale. LITIRESO – Awon eka ede Yoruba: Ohun ti eka ede je; Awon eka ede to wan i ipinle kookan OSE 10. OSE KEJEGBOLOHUN ONIPONNA ITUPALE GBOLOHUN ONIPONNA. Litireso: kika iwe litireso ti ijoba yan. Ayeye ere onile-jile ti o koja ni ile iwe mi 2. 1 Ede: Atunyewo fonoloji ede Yoruba. Orisiirisii ni awon eya gbolohun ti o wa ninu ede Yoruba. Orisirisi ona ni a le pin gbolohun ede Yoruba si, Awon ni: gbolohun eleyo oro ise, OSE KEJOAKORI ISE: - Eya awe gbolohun Yoruba AKOONU: - Olori awe gbolohun Awe gbolohun afara he Gbolohun Yoruba to kun maa n ni itumo kan, o si maa n ni ise kan pato to n je. Get full lesson notes and plan in PDF by reaching out to us. Bi aya ba moju oko tan, alarina a yeba. Daruko orisii egbe awo ti o wa. Ohun ni ohun ti oro ise maa n fi abo le lori ninu gbolohun. Won fun gbolohun ede Yoruba ni oruko gege bi ise ti o n se. EDE: Silebu Ede Yoruba. ‘O je e. Ara orisii gbolohun ni gbolohn olopo oro ise wa. Apola le je eyo oro kan, o si le je meji tabi ju bee lo. Download Comprehensive Senior Secondary School Lesson Notes for Yoruba Language SSS2 2nd term in PDF or DOCUMENT - Edudelight Store. 3 ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KEJI 1 EDE: Ihun orisii awe gbolohun po di odidi gbolohun. CLASS-; SS1 ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KEJI Ose kinni- Ede-Atunyewo awon isori oro oro aropo oruko oro aropo afarajoruko oro atokun oro asopo oro-ise Asa- Oge sise Litireso-Itupale asayan iwe litireso Ose keji Ede- Awon isori gbolohun gege bi ihun won. Read Also. Mo ti lo ki ore mi de Gbogbo ilu gbo pe oba waja Akekoo naa mura ki o le gbebun SECOND TERM E-NOTE SUBJECT; YORUBA. LIT: Itesiwaju lori Asayan iwe litireso ti ijoba yan. Apeere aroko ajemo Ohun tí a pè ni òfin yìí ni bi elédè se ń so èdè rè bí ìgbà pé ó ń tèlé ìlànà kan. Títí rà wọ́n. Iru oro bee ni rakorako, fiofio, tonitoni. Ni opin idanilekoo, awon akekoo yoo le:: i. S. AP. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Se Iye nnkan ni a n fi eyin eyi toka ninu gbolohun. A personalized learning resource for all agesClassNotes. (oluwa) (oro ise) (abo) Asa: Atünyewo ise saa kiini lori ede, asa ati litireso. Omaa n fara he olori awe gbolohun ni. Ori re ni oro ise maa n dale lori. oriki ati ilana kiko aroko yoruba pelu apeere yorÙbÁ jss 1 first term lesson note week 9; Àrọ̀kọ̀ atonisona alapejuwe yoruba jss 1 first term lesson notes week 10; JSS1 Yoruba Lesson Note -Second Term academic session. 3. Fun ApeereWa-je oro onisilebu kan nitori pe ami ohun kan ni o wa lori re. Ó lọ sí ilé ìwòsàn. 'Gbólóhùn èdè Yorùbá ni a lè pè ní odidi ọ̀rọ̀ tí ó pé, tí ó ní olùṣe ati abọ̀ nínú tí ó sì bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú lẹ́tà ńlá. - Discover insightful and engaging content on StopLearn Explore a wide range of topics including Notes. com. LIT: Litireso alohun to je mo aseye: [ege] ati agbegbe to n lo won. ose keje: ede: ihun gbolohun olopo oro ise ati atupale. gbolohun oniponna le je eyo oro tabi apola kan ni o maa ni ponna. eui ni ipede tabi gbolohun ti a lo oro asopo lati so gbolohun meji tabi ju bee lo po di eyo gbolohun kan soso. Lesson Oun, eni, emi, awon, eyin, awa, ati ibo. Lesson note on Yoruba for SS2 Third Term – Edudelight. Apeere; Fun mi ni omi mu; Jowo maa bu mi mo; Gbolohun Ayisodi:- Gbolohun The content is just an excerpt from the complete note from Yoruba Lesson Note from SS1 Osa keji Ede-Awon isori gbolohun ede Yoruba gege bi ihun. Kiko ni a maa n ko o. Apeere: - Awon eniyan mo pe ounje won Bisi daba a moto rira Alaga feiyawo OSE KEJIAPOLA ORUKO (Phrases)Apola ni apa kan gbolohun ti o le je oro tabi akojopo oro. Oro aropo-oruko. Bi apeere: Ade ra iwe ede Yoruba. GBOLOHUN ALAKANPO. ASA – Itesiwaju lori oruko ile Yoruba, oruko eni, emi, awon, eyin, awa, ati ibo. Ose Kin-In-Ni: Atunyewo ise saa kin-in-ni. ASA – Atunyewo asa iran ra eni lowo owe, aaro, obese, esusu, ajo. Ose keta Iye nnkan ni a n fi eyin eyi toka ninu gbolohun. The content is just an excerpt from the complete note from Yoruba Lesson Note from JSS1 – JSS3. Ose Keji: Ede: Orik ati eya gbolohun Ede Yoruba pelu apeere Asa: Oge sise ni ile Yoruba Litireso: Orin ibile to je mo asa igbeyawo, pipa ogo obinrin SS 3 YORUBA FIRST TERM SCHEME OF WORK LESSON NOTE PLAN oro aropo oruko, oro ise, sise itupale gbolohun kekere si isori oro. Gbolohun Asa itesiwaju lori awon owe ile Yoruba Lit Kika iwe litireso apileko ti ijoba yan 3 Ede Aayan ogbufo. Lara apola inu ede Yoruba ni apola oruko, aopla ise, ati apola aponle. Gbólóhùn Eleyo oro Download Comprehensive Senior Secondary School Lesson Notes for Yoruba Language SS2 2nd term in PDF or DOCUMENT - Edudelight Store. Gbolohun yii maa n ju eyo oro-ise kan lo, oro-ise inu gbolohun yii le je meji tabi meta. Orisii Oruko, Ise Oro-Oruko ninu Gbolohun; ASA: Asa- Asa Isomoloruko: Amutorunwa, abiso, inagije abbl. EKO ILE. ÀSÀ: Iwulo ede Yoruba [oro siso]. orisiirisii isori oro ni o le jeyo po ninu apola-ise. Apeere: Dolapo ra keke. Free secondary school, High school lesson notes, classes, videos, 1st Term, 2nd Term and 3rd Learn online with very engaging video lessons, ebooks and audio lessons Toka si isori kookan ninu gbolohun. Related Articles. Oro –oruko ni awon oro ti won le da duro nipo oluwa,abo tabi eyan ninu gbolohun. Pipapo apa oro eyo kan ni a mo si isunki. 4. Check below for the appropriate link Gbolohun olopo oro-ise: gbolohun yii naa ni a mo si gbolohun onibo. LIT: Itupale ewi OSE KEJIEDE GBOLOHUN ONIBOAKOONU Oriki gbolohun onibo Apeere atoka/wuren gbolohun onibo Apeere gbolohunNi opo igba a maa n pe gbolohun onibo ni gbolohun olopo oro ise tabi gbolohun alakanpo. Eko ile Yoruba, awon eko ti awon obi maa n ko omo lati kekere ni a n pe ni eko-ile. Igi ga Gbolohun ni Ilana Ise /ise ti o n je: apeere gbolohun alalaye, ase, ibeere, kani, ayisodi, View More. Won maa n jeyo ti a ba n so nipa asa Yoruba kan. Apola Aponle Oniba: Apola aponle yii maa n toka si isesi, iba tabi bi a se n se nnkan JSS Two Yoruba JS2 ORISI GBOLOHUN Gbolohun ni iso ti o ni itumo kikun. Awon naa ni:- Awon oro-aponle aiseda. LIT: Itupale ewi apileko. Apola – oruko le je eyikeyii ninu awon wonyi. Iji ja. ISORI GBOLOHUN – EduDelightTutors JSS1 Yoruba Language Scheme of work with Lesson notes Content for second term. Gbolohun alakanpo ni gbolohun kan ati gbolohun miran ti a so papo bi apeere:PELU ,AMO abbl . ASA – Afiwe asa Isinku abinibi ati eto sinku ode oni. Oriki Abuda oro aropo oruko Ate oro aropo oruko Irisi oro aropo oruko. 1 OLORI AWE GBOLOHUN Olori awe gbolohun ni gbolohun to le da duro pelu itumo. Abuda oro aropo oruko. Aroko alariyanjiyan je aroko ti a ti maa n jiyan lori nnkan kan. Oriki Olori Awe Gbolohun (Isori Awe Gbolohun) Awe Gbolohun Afarahe Orisii Awe Gbolohun Afarahe. Baba ko ebe. Apeere; Olu ke Back to: Yoruba Primary 2 Tití ń ṣe àìsàn. Oro-oruko kan soso pere. Apeere: Kunle sare tete lo pon omi Gbolohun alakanpo: o maa n gbolohun meji ninu. ₦ 1,300. Bola ati Sade wa si ile iwe ii. Welcome to Stoplearn. (oro aponle). . Bi apeere; Wa ri mi (olori awe gbolohun) bi o ba de ( awe gbolohun afarahe) O ya mi lenu ( olori awe gbolohun ) pe o gbo ( awe gbolohun afarahe ) Ma ra oko fun baba mi (olori awe gbolohun ) ti mo ba dolowo ( awe gbolohun afarahe ) EDE – Itesiwaju eko lori oro ise; Alaye lori orisii ati ilo re ninu gbolohun ASA – Afiwe asa Isinku abinibi ati eto sinku ode oni. A maa n lo awon wunien yii dipo oro oruko ninu gbolohun. Tobi jeun dieBolu n rin kanmokanmo bo. ‘ti’ ni wunren atoka won. Ile laawo ki a to somoloruko. Bolu ti de? Ko tii de IWE ITOKASI. Mo ti lo ki ore mi de; Gbogbo ilu gbo pe oba waja; Akekoo naa mura ki o le gbebun; Awe Gbolohun Afarahe: Awe gbolohun afarahe je awe gbolohun ti ko le da duro pelu itumo. Awon oro-aponle aseda. Tunde ni iwa omoluabi sugbon ko ni owo iii. OSE KARUN-UNAROKO AJEMO ISIPAYAAroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Dide duro; E dake jeje; Wa ri mi Gbolohun Ebe: A n lo gbolohun ebe lati fi bebe fun ohun kan. Orisirisi ona ni a le pin gbolohun ede Yoruba si, Awon ni: gbolohun eleyo oro ise, Koko Ise: Ise oro Ise ninu gbolohun. OSE n sise eyan : nigba ti oro oruko meji ba tele ara ninu gbolhun, eyan ni oro oruko keji . Isori oro +ninu gbolohun Atunyewo lori Aroko ajemo isipaya, Atunyewo lori silebu ede, Atunyewo aroko onisorongbesi. Eni fun ni lobinrin pari ore. Mama se isu ewura. 2. Itesiwaju lori eko nipa iro ede; Owe ASA. Eyi ni awon gbolohun gege bi ihun won; Gbolohun eleyo oro-ise Gbolohun olopo-oro-ise Gbolohun alakanpoGbólóhùn eleyo oro-ise-: ni gbolohun ti o maa n ni eyo oro ise kan EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Apola oruko maa n duro gege bii oluwa ninu gbolohun. Irufe gbolohun yii ni a tun mo si gbolohun kukuru. Our contributors on this subject are well trained and highly qualified tutors and we hope the students find this very useful. Fadekemi we gele. Apeere. Mo OSE KEFAAKORI ISE (EDE): AROKO ALARIYANJIYAN AKOONU: Itumo aroko alariyanjiyan. 00 Order Now; DISCOUNT 13% Complete SS2 Mathematics Lesson Note ₦ 1,500. OSE KERINAKORI ORO: - EYA GBOLOHUN EDE YORUBA AKOONU: -- Gbolohun eleyo oro ise - Gbolohun olopo oro ise - Gbolohun alakanpo - Gbolohun ase - Gbolohun ibeere Gbolohun ni ipede ti o kun. Lesson note on Yoruba for SS2 Second Term - Edudelight. ASA: Atunyewo awon asa to jeyo ninu ise olodun kin-in-ni LIT: Atunyewo awon ewi Apeere konsonanti konsonanti aranmupe asesilebu (n) - Tade n je isu - Mo n lo - Ba-n-gba-de - o Gbolohun Ase: Eyi ni gbolohun ti a fi n pase fun eni ti a n ba soro. Bi apeere: Igi ope naa ga fiofio Oko naa run womuwomu. APA KEJI . Dahun ibere meta ni abala yii, sugbon nomba waanu (1) se Pataki. ALIFABEETI JE AKOJOPO LETA TI ASE AKOSILE RE GEGE BI IRO NINU EDE YORUBA. 00 Order Now; Second Term SS2 French Lesson Note ₦ 500. Tolu fo aso. Gbolohun eleyo oro ise o maa n ni eyo oro ise kan. Irufe oro-aponle inu ede Yoruba pin si orisii meji. Gbolohun eleyo oro ise, gbolohun olopo oro-ise, sise akojopo gbolohun eleyo oro-ise. Oro ise asodidi gbolohun(oro apase):Awon oro yii maa n waye bii gbolohun ase bakan naa won le duro bii gbolohun. Iro faweli ati iro konsonanti aranmupe asesilebu ni o maa n sise gege bi odo silebu. Won n rin, won n yan, won si n se oge. Ninu gbolohun, a maa n ri orisirisi isori oro paapaa julo oro ise gege bi opomulero gbolohun. Faweli ati ohun. Ayo ko le da mi. Apeere iwe to samulo awon orisa ni NINU GBOLOHUN ASA: OWE ILE YORUBA LITIRESO: KIKA IWE EWI TI IJOBA YAN OSE KOKANLA ATI IKEJILA: EDE: ATUNYEWO EKO LORI ISEDA ORO . Ara odidi gbolohun ni a ti fa awe gbolohun yo. Y (2006) Imo, Ede, asa ati Litireso Ede Yoruba Copromutt Publishers o. Asa- Oge sise Aso wiwo laarin okunrin ati - OSE KERINEYA AWE GBOLOHUN AFARAHEAKOONU:- Awe gbolohunafarahe Olori Awe GbolohunORISII AWE GBOLOHUN AFARAHEOrisii awe gbolohun afarahe meta ni o wa ninu ede Yoruba, awon meteeta ni: -(a) Awe Gbolohun Afarahe Asodoruko: eyi maa n sise oro oruko ninu gbolohun. Orisiirisii oro aponle ti ani ninu ede Yoruba ni: apola aponle oniba, apola aponle alasiko, apola aponle onibi, apola aponle onidii, apola aponle alafiwe. Subscribe now to gain full access to this lesson note Take Me There . Oriki Ibi ti o ti n jeyo. 2 Ede: Aroko Gbolohun Olopo Oro-Ise: o maa n ni ju eyo oro ise kan lo. Ijamba oko kan ti o sele ni osodi ILANA ISE SAA KEJI ISE : EDE YORUBA KILAASI: J. Ayo ko OSE KESAN-ANEYA AWE GBOLOHUN Gege bi a so saaju pe awe gbolohun pin si meji: olori awe gbolohun ati awe gbolohun afahe. LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan: 7 Salaye awon gbolohun yii pelu apeere mejimeji fun ikookan. Gbolohun olopo oro-ise: gbolohun yii naa ni a mo si gbolohun onibo. beeré ohun ti ko ye won iv. 00 Current price EDE – Gbolohun ibeere – awon iwure ti a fi n se ibeere da, nko, nje, taki. EDE: Oro Aropo-Oruko; ko apeere gbolohun oniponna marun-un sile. A le pin ona ibanisoro laye atijo si ona meji Pataki. ASA – Igbagbo ati ero Yoruba nipa Ajinde leyin iku. Itupale eyo oro oniponna ninu gbolohun. OSE KETA ORISIi EYA AWE GBOLOHUN AFARAHE ASAPONLE (a) Awe gbolohun afarahe asaponle alafiwe gbolohun yii maa n se afiwe nnkan meji wunren “bi” tabi “bi” ni atoka re Ade nkorin bi eye se nkorin. Aroko (Leta gbefe), EDE – Oro/gbolohun onipoona: Itumo poonaAkojopo awon oro onipoonaAlaye lori itumo oro ati gbolohun onipoona ASA Apapo oro – oruko ati awe gbolohun. Bola jeun ni ori tabili Sade ra aso ti ko ni iho lara Ojo gbodo jeun ki o to lo oogun re. Onkowe, itan ni soki ati awon amuye miiran: 2: EDE – Itesiwaju eko lori isori gbolohun gege bi ihun won. Awon litireso apileko ewi. Obe ti bale ile ki i je iyaale ile ki i se. The content is just an excerpt from the complete note from Yoruba Lesson Note from SS1 – SS3. o tumo si pe . Olori Awe Gbolohun: Olori awe gbolohun ni abala apakan odindi gbolohun ti o le da duro pelu itumo. Irufe gboloun yii maa n ni ju eya kan lo. Ihun silebu. Ere boolu alafessegbe kan ti mo wo 2. Se o maa lo? N ko lo. ’ ‘ewure je agbado Bola’ ‘ewure je agbado re. Oro ise alakanpo: A le pe oro ise yiii ni ‘Asinpo’. Ose Be the first to review “Complete JSS1 Yoruba Lesson Note GBOLOHUN ABODEAKOONU: Itumo gbolohun abode Apeere gbolohun abodeGbolohun abode ni gbolohun ti ki i ni ju eyo oro ise kan lo gege bi a ti so saaju. Gbolohun eleyo oro ise a maa je olori awe gbolohun, nitori wi pe eyo oro ise kan ni o wa ninu re ti ko si gun gbooro. Ona ibanisoro ti ode oni 1. GBOLOHUN ASE. Apapo konsonanti, fawli ati ohun ninu oro. Oriki Ati Eya gbolohun ede Yoruba pelu apeere (sentence) Ede:- Atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba. Oro aropo-afarajoruko. Primary Video Lessons Primary Audios Primary Books Junior Secondary Video Lessons Junior Secondary Audios Junior Se àpẹẹrẹ orisii awon gbolohun meteeta naa. Free secondary school, High school lesson notes, classes, videos, 1st Term, 2nd Term and 3rd OSE KEJEGBOLOHUN ONIPONNA ITUPALE GBOLOHUN ONIPONNA. SECOND TERM YORUBA LANGUAGE – JSS ONE ETO ISE FUN SAA KEJI Ose Kin-In-Ni: Atunyewo ise saa kin-in-ni Ose Keji: Ede: Orik ati eya gbolohun Ede Yoruba pelu apeere Asa: Oge sise ni ile Yoruba Gbolohun ni Ilana Ise/ise ti o n je: apeere gbolohun alalaye, ase, ibeere, kani, ayisodi, Gbolohun Alalaye: a maa n fi se alaye. Olori awe gbolohun ati awe gbolohun afaraheGbolohun ni ipede ti o kun ti o si loorin. Apeere; Ounje Jumoke ni mo fe je; Awa egbe ode ilu niyi Olori Awe Gbolohun: Olori awe gbolohun ni abala apakan odindi gbolohun ti o le da duro pelu itumo. ii Awe gbolohun afarehen. LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan: 7 Akọ́tọ̀ Òde-Òní Yorùbá JSS 1 First Term Lesson Notes Week 5; Onkà Yorùbá Láti Oókan De Aadota (1-50) Yoruba JSS 1 First Term Lesson Notes Week 6; OONKA Láti Aadọta De Ọgọrun-ún (51-100) Yoruba JSS 1 First Term Lesson Notes Week 8; ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE YORÙBÁ JSS 1 FIRST TERM LESSON NOTE WEEK 9 Ose kewa: Ede-atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba Asa-asa iwa omluabi Litireso-kika iwe litireso apileko ti ijoba yan. Aroko atonisona Alapejuwe; Oye jije ati ohu elo oye jije. Ore mi ti o lo Bi asa se jeyo ninu ede Yoruba. (oluwa) (oro ise) (abo) OSE KEJE IBASEPO LAARIN AWE GBOLOHUN ATI ODINDI GBOLOHUNGbolohun ni ipede ti o kun pelu ituno nigba ti awe gbolohun je apa kan odindi gbolhun Ara odindi gbolhun ni a ti fa awe gbolohun yo. Adebisi n soro fatafata ni kilaasi. ORUKO APEERE ORI ORO AROKO ASOTAN/ONIROYIN 1. Apeere: Apeere: Olu je buredi ati eyin. Orisirisi bii iku se n pani apeere, aisan, ijamba lorisirisi, afomowofe ati bee bee lo. Orimogunje, K. Lesson Note for Primary School Download (First, Second and Third Term) Ose Keji: Ede: Orik ati eya gbolohun Ede Yoruba pelu apeere . LIT: Akoonu orin etiyeri ati Gbolohun ni Ilana Ise /ise ti o n je: apeere gbolohun alalaye, ase, ibeere, kani, ayisodi, View More. Click here to gain access to the full notes. Daruko awon ona ti a n gba lati gba gbese ni Ninu apola-ise ni koko gbolohun maa n wa. A fún àwon gbólóhùn Yorùbá ní orúkọ gégé bí íse tí won ń se. Apeere/itupale oro-oniponna ninu gbolohun. ASA: EkoIle LIT: Itupale Asayan iwe litireso ti ijoba yan. LITIRESO – Awon eka ede Yoruba: i OSE KEJIORO AROPO ORUKO. Apeere: - Eyo konsonanti aranmupe ase silebu le da duro bii silebu apeere; Ko m ko – ko – n-ko; Gbangba – gba – n-gba; Ogedengbe – o – ge – de – n-gbe; Lesson Note on Music JSS3 (BASIC 9) Third Term. Ose Keji: Ede: Orik ati eya gbolohun Ede Yoruba pelu apeere. Isori oro: Oro oruko Oro àròpọ̀ oruko Oro apejuwe Oro atọ́kùn Oro asòpò Àlàyé kikun lori ipo ati ise won ninu gbolohun. Gbogbo awon ti a fala si nidi yii ni a pe ni olori awe OSE KETA IYATO TO WA LAARIN APOLA ATI AWE GBOLOHUNAwe gbolohun ; - Laisi gbolohun, ko le si awe gbolohun rara. Ona mejeeji naa ni:- 1. Awon litir//so Apileko – Ere onitan. Ó lo oògun náà EKA ISE ASA. Bi apeere:-Dupe 'pon' omi. LITERATURE IN ENGLISH LANGUAGE SECOND TERM SCHEME OF WORK FOR JSS1 OSE KEFAORO – APONLEAKOONUOro-Aponle je oro ti o maa n pon oro-ise ninu gbolohun. Gbolohun ni Ilana Ise/ise ti o n je: apeere gbolohun alalaye, ase, ibeere, kani, ayisodi, Gbolohun Alalaye: a maa n fi se alaye. ise ni oro tabi akojopo oro to n toka si isele tabi nkan ti oluwa se ninu gbolohun. Apeere: - Awon eniyan mo pe ounje won Bisi daba a moto rira Alaga feiyawo Gbolohun eleyo oro-ise tabi gbolohun abode: eyi ni ipede tabi afo ti o ni oro-ise kan ninu. O ye ki n lo 5. OSE KEWAAGBOLOHUN EDE YORUBAgbolohun ni ipede ti o kun pelu itumo kikun. 00 Original price was: ₦1,500. Ibere gbolohun ni o saba maa n wa. Apeere:Olu lo si ojaRanti sunWon mu osanOmo yii rewaAde subu yakata. AROSO ASOTAN/ONIROYIN. Apola oro oruko tun le duro ni ipo abo ninu gbolohun. Ninu aroko yii alaroko gbodo maa ko si otun ati osi. Awon iro odo silebu ni a maa n gbo ju ninu oro. Bi apeere: Omode meta n sere. Oro-ise ati oro-oruko ni ipo abo. EDE – Awe gbolohun ede Yoruba: Oriki ati alaye kikun lori awe gbolohun; Orisi awe gbolohun; Olori awe gbolohun; Awe gbolohun afarehen; ASA – Igbagbo ati ero Yoruba nipa Ajinde leyin iku. GBOLOHUN ALABODE( Simple sentence)Eyi no gbolohun kukuru, ti ko ni ju eyo oro-ise Kan lo. OSE KEJI: EDE: Gbolohun onibo (oriki pelu apeere) ;ASA: Asa igbeyawo nile Yoruba (eto igbeyawo) ifojusode,iwadi abbl Pataki ibale ; LIT:Kika iwe apileko oloro geere ti ijoba yan OSE KETA: EDE: Gbolohun onibo-Eya gbolohun onibo gbolohun onibo apejuwe, asaponle,asodoru; LIT : Kika iwe apilleko oloro geere ti ijoba yan ; ASA: Igbeyawo aye ode oni. 1 Corpromutt Publisher Nig Ltd. Atunyewo orisirisi eya litireso . ISE ORO ORUKO NINU GBOLOHUN Oluwa (Subject): Oluwa ni oluse isele inu gbolohun. Adebayo, F. {vi} Eyan awe gbolohun asapejuwe/ Awe gbolohun asapejuwe:- Ni ara gbolohun ni a ti n seda eyan yii Ninu apeere oke yii, awe gbolohun afibo ko ni itumo, oro abo ni ti o ni lo olori gbolohun fun itumo kikun. O maa n se afikun itumo fun apola-ise, ti yoo si je ki itumo re si tubo ye ni yekeyeke. AKOONU:- Silebu ni ege oro ti o kere julo ti eemi le gbe jade leekan sosoIye ohun ti o ba wa ninu oro ni iya silebu ti oro naa yoo ni. Amuye ewi, koko ewi abbl. Ko si ohun ti a o le ko si eniyan afi eyi ti a ko fe ko. SUBJECT: YORUBA LANGUAGE CLASS: JSS3. So ise ti okookan n se ninu gbolohun. Mo,ise Agbe, ise ode. d. Gbolohun alakanpo: eui ni ipede tabi gbolohun ti a lo oro asopo lati so gbolohun meji tabi ju bee lo po di eyo gbolohun kan soso. Gbólóhùn ni ìpèdè tí ó kún, tí o sí ní ìse tí ó ń jé. A kuru yejo: ni a n pe o. Kika iwe apileko ti ijoba yan. Eto aabo ilu ati ipati awon obinrin n ko ninu eto ogun. Ise kilaasi OSE KETAEDE AWE GBOLOHUNAwe gbolohun ni apakan odindi gbolohun. {vi} Eyan awe gbolohun asapejuwe/ Awe gbolohun asapejuwe:-Ni ara gbolohun ni a ti n seda eyan yii lati fi kun itumo oro-oruko. Akanlo - ede oni – odidi – gbolohun- Apeere: oba waja, Ekun lo, Erinwo Oba ilu ko Akara tu sepo, awoya, okete boru Asiritu A-gbo OSE KESAN-ANAWON ISORI GBOLOHUN YORUBA GEGE BI ISE WON. a. FIRST TERM E-LEARNING NOTE. AKOONU: -Oro aropo-afarajoruko ni isesi to frajo ti oro-oruko sugbon o mu eto iye ati eni lara abuda oro aropo oruko. 6 ÈDÈ: Onka ookanlelaadota de ogorun [51-100] APOLA ORUKO:- Ni oro tabi akojopo oro to le duro gege bi Oluwa, abo pelu eyan tabi laisi eyan ninu gbolohun. Wa ri mi Gbolohun Ebe: A n lo gbolohun ebe lati fi bebe fun ohun kan. jiroro lori ohun ti o ye won ninu eko éteyinwa iii. Oro asopo bii, ati, sugbon, omo, tabi, abbl. Pataki orin lawujo Yoruba. Y (2014) IMO, EDE, ASA ATI LITIRESO YORUBA fun ile eko girama agba S. EYA ORO ORUKO. ORO-APONLE. Awa naa je eba metameta. Ade jeun yo. Gbolohun alakanpo: o maa n gbolohun meji ninu. Faganwa fi igbagbo yii han ninu awon iwe itan aroso. Apola oro oruko le duro ni ipo eyan ninu gbolohun. Oro-Ise agbabo ati Eyan. Isomoloruko omo egbon mi obinrin. Abuda oro aropo afarajoruko. Onka lati ookan lelaadota de ogorun-un (51-100) Asa ati ohun-elo isomoloruko. Awon egbe wa n yoo se ajodun lose yii. Fun asa isinku ni oriki; Ko orisi oku sin sin ni ile Yoruba mewaa; SECOND TERM LESSON NOTE PLAN SCHEME OF WORK FOR NURSERY, KG, PRIMARY AND SECONDARY SCHOOLS; All Subjects Primary 1 Second Term Lesson Notes; EDE – Gbolohun ibeere – awon iwure ti a fi n se ibeere da, nko, nje, taki. Lilo eya ara fun ibanisoro a. Ise Agbe. AKOONUOro aropo oruko ni a maa n lo dipo oro-oruko ninu apola oruko. I 155-156. Apeere ori oro aroko alalaye ni : Ise ti mo fe se GBOLOHUN ABODEAKOONU: Itumo gbolohun abode Apeere gbolohun abodeGbolohun abode ni gbolohun ti ki i ni ju eyo oro ise kan lo gege bi a ti so saaju. Daruko orisii aso marun-un fun okunrin ati obinrin. Awon oro aropo afarajoruko ni wonyii; - emi,iwo,oun,awa,eyin, awon. Alaafia to oyo. Ise Oro Ise:Oro Ise ni o maa n toka isele inu gbolohun. Oro- oruko pelu awe gbolohun . Oro aropo oruko ni eto to n toka si iye bi eyo tabi opo. Bi apeere: ASA IGBEYAWO. E je ki a se itupale irufe gbolohun yii tabi ki a so pe ki a wo tifuntedo gbolohun onibo. OSE 9. Fun apeere aroko lori obinrin dara ninu ise ile ju okunrin lo. Ara gbolohun ni a ti fa awe gbolohun yo. EBA Gbolohun Iyisodi-: ni a fi n ko isele. Iyen ni pe alaroko gbodo maa ko aroko lori ero meji. Bi apeere eyan awe gbolohun asapejuwe ni a fala si nidii yii: Akanlo – ede apola – Apeere Jawe dimu, papoda, lo iwale asa, di oloogbe, fi ile bora, ta teru nipaa Ki eniyan ku Baba naa ti ta teru ko ina lobe je tan eniyan je Awon oloselu n fi buredi ko ni lobe je. ASA: OWE ILE YORUBA. Com. Mo je akara. Lilo eya ara lati fi ba ara eni soro 2. Ade n rin kanmokanmo bo. Asa: Oge sise ni ile OSE KETAAPOLAAKOONU: - Ki ni a n pe ni apola Ki ni apola oro oruko Ise ti apola oro oruko n se ninu gbolohun Ki ni a n pe ni apola ise Ise ti apola ise n se ninu gbolohunApola ni akojopo oro ti o n di apa kan gbolohun. Orisiri apola lo maa n di apa kan tabi odidi gbolohun. Awon egbe wa n yoo se ajodun SS 3 FIRST TERM LESSON NOTE YORUBA – EduDelightTutors. Àpẹẹrẹ:Bólú je èbàBàbá kọ ebèÈyà gbólóhùn. ASA: Isse abinibi. Apeere: Bolu ko jeun. Gbolohun olopo oro-ise naa ni a mo si gbolohun onibo. Fadeke n jenu waduwadu. Ng offers practice exercises, lesson, and a personalized learning dashboard that empower learners to study at Third Term SS 1 Lesson Notes Yoruba – Examination Questions. Yoruba lesson note for SS2 First Term Sise asunki odidi gbolohun di oro-oruko. O wa. O. Ile awa dun. IHUN APOLA ORUKO. Apeere:- Ise akowe dara OSE KARUN-UNAROKO ALALAYE KIKO AROKO ALALAYE (APEERE)ISE TI MO FE SE LOJO IWAJUIru ise wo ni o fe se lojo iwajuAlaye lekunrere lori ise naaIdi ti ise naa fi wu oIru ipo wo ni ise yii le gbe o deEro re lori ise yii. ose kefa: asa: igbese ti agbe yoo gbe ki ire oko to jade. Emi ko ri Bola. EKA ISE: ASA. E dake jeje d. Sade ‘ra’ bata. Ayo ko le da mi [ se eda mi ]. Bola wa iii. OSE KESAN-ANORO ORUKOOro oruko (noun) ni awon oro ti o n sise Oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. dåhün ibééré Iori åkori eko: Lit: Atünyewo ise saa kiini lori ede, asa ati litireso. Scribd is the world's largest social reading and publishing site. EDE – Apola ninu gbolohun ede Yoruba: Apola oruko 4. ASA: Isinku ni ile Yoruba 1: orisii oku ati bi a se n sin won, oku riro ati etutu oku sise bi ti eleegun. ‘Bola jeun o si yo’ je apeere gbolohun (a) Olopo oro ise (b) alakanpo (d) aijowa 5. Ise asetilewa: ko apeere ewi alohun Yoruba marun-un. O je ipede ti ko ni ju apola-oruko ati apola-ise kookan lo. Gbólóhùn jé ìsọ tí ó ní ìtumo kíkún. Lesson Note on Yoruba JSS1 (Basic 7) First Term. Gbolohun Ibeere: SECOND TERM. E dide jokoo ii. Ti a ba yo oro ise: pon, ra, ro kuro ninu awon gbolohun oke 4 ÈDÈ: Akoto; Awon oro ti a sunki [alanu= alaanu ati pataki yiyamo sidi oro ÀSÀ: Awon eya Yoruba, ounje won ati awon nnkan pataki nipa won LIT: Ipa ti litireso ko lawujo Yoruba. Agba ki I wa loja ki ori omo tuntun wo. Oro aropo Apeere; Molosioko; Babawasiibe . Dide duro b. Eya gbolohun; Asa igbeyawo ni ile Yoruba (igbeyawo ode-oni) Kika iwe Asa ona ibanisoro Ona ibanisoro ni awon ona ti awon Yoruba maa n gba lati ba ara won soro lorisirisi yala laye atijo ati ni ode-oni. Apeere:- Mo je eba Iwo ri olopaa Ade pa aja. Litireso: Awon ewi alohun ti o je mo esin abalaye iyere ifa, Sango pipe. Gbolohun: Oro-oruko ti a seda: Oluwa to sin. Oro Ise ni emi gbolohun. Ere boolu alafesegba kan ti mow o 3. Eya gbolohun nipa ise won; Asa igbeyawo ni ile Yoruba. Inu igi bii igi iroko, igi agbalumo, inu igi ibepe, igi ahusa, agbo ogede ni won ngbe. ISE-:EDE YORUBA CLASS: SS1 ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KETA Ose: EDE: Isori oro;Oro Oruko: Oriki, Orisii Oruko, Ise Oro-Oruko ninu Gbolohun ASA: Asa- Asa Isomoloruko: Amutorunwa, abiso, inagije abbl. A le pin leta kiko si orisii ona meji pataki. Oriki ati liana kiko aroko Yoruba pelu apeere; Isomoloruko II. LITIRESO – Awon eka ede OSE KEJIORI-ORO- AWON ISORI GBOLOHUN GEGE BI IHUN WON. Akanpo gbolohun eleyo oro-ise meji nipa lilo oro asopo ni gbolohun alakanpo. Pipa aroko 3. Nibi ti a ba ti pa iro je, alafo yoo wa nibe, a o wa pa iro mejeeji po di eyokan. Awon naa ni awe gbolohun afarahe ati olori awe gbolohun. (Oluwa) (oro ise) (abo) Iyawo bi omo. Apeere: Aso re OSE KEJIORI-ORO-;SILEBU EDE YORUBA Oriki. Apola Oruko (noun phrase): okan ninu apola oro ti a hun po di gbolohun ni apola oruko. Olu n 'ro' amala ni ori ina. LITIRESO – Kika iwe litireso ti ijoba yan: 6: EDE – Atunyewo ami ohun ati silebu. Awon iran/orile ti o maa n jagun ni ile Yoruba laye atijo. Bola jeun ni ori tabili Sade ra aso ti ko ni iho lara ILANA ISE SAA KIN-IN-NI ISE: EDE YORUBA KILAASI: JSS2 ILANA ISE OSOOSE FUN SAA KIN-IN-NI 1 EDE: Sise atunyewo fonoloji ede Yoruba. JSS 2 THIRD TERM LESSON NOTE PLAN YORUBA – EduDelightTutors NINU GBOLOHUN. Ti a ba yo oro ise: pon, ra, ro kuro ninu awon gbolohun oke wonyi, ko lee ni itumo. yqni qne rhvtz jib rpwgl pipame rcuo ikyqn savm jgqhow